Kronika Kinni 11:29-32 BIBELI MIMỌ (BM)

29. Sibekai, láti inú ìdílé Huṣati, ati Ilai, láti inú ìdílé Aho;

30. Maharai, ará Netofa, ati Helodi, ọmọ Baana, ará Netofa;

31. Itai, ọmọ Ribai, ará Gibea, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini, ati Bẹnaya, ará Piratoni;

32. Hurai, ará etí odò Gaaṣi, ati Abieli, ará Aribati;

Kronika Kinni 11