1. Adamu bí Seti, Seti bí Enọṣi.
2. Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi;
3. Jaredi bí Enọku, Enọku bí Metusela, Metusela bí Lamẹki;
4. Lamẹki bí Noa, Noa bí Ṣemu, Hamu, ati Jafẹti.
5. Àwọn ọmọ Jafẹti ni Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki ati Tirasi.