Kronika Keji 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn tí o bá yipada kúrò lọ́dọ̀ mi, tí o kọ àṣẹ mi ati òfin tí mo ṣe fún ọ sílẹ̀, tí o sì ń lọ bọ oriṣa, tí ò ń foríbalẹ̀ fún wọn,

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:12-22