Kronika Keji 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, OLUWA fara han Solomoni lóru, ó ní, “Mo ti gbọ́ adura rẹ, mo sì ti yan ibí yìí ní ilé ìrúbọ fúnra mi.

Kronika Keji 7

Kronika Keji 7:4-17