Kronika Keji 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ṣé ìwọ Ọlọrun yóo máa bá eniyan gbé lórí ilẹ̀ ayé? Bí ọ̀run ti tóbi tó, kò gbà ọ́, mélòó mélòó ni ilé tí mo kọ́ yìí?

Kronika Keji 6

Kronika Keji 6:8-27