Kronika Keji 33:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, bíi Manase, baba rẹ̀, ó rúbọ sí gbogbo oriṣa tí baba rẹ̀ ṣe, ó sì ń bọ wọ́n.

Kronika Keji 33

Kronika Keji 33:17-25