Kronika Keji 24:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọba pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe àpótí kan tí àwọn eniyan yóo máa sọ owó sí, kí wọ́n sì gbé e sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA.

Kronika Keji 24

Kronika Keji 24:5-15