Kronika Keji 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Sibẹsibẹ wọn yóo jẹ́ ẹrú rẹ̀, kí wọ́n lè mọ ìyàtọ̀ ninu pé kí wọ́n sin òun OLUWA, ati kí wọ́n sin ìjọba àwọn ilẹ̀ mìíràn.

Kronika Keji 12

Kronika Keji 12:1-10