Kọrinti Kinni 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, ohun tí mò ń sọ nìyí. Àkókò tí ó kù fún wa kò gùn. Ninu èyí tí ó kù, kí àwọn tí wọ́n ní iyawo ṣe bí ẹni pé wọn kò ní.

Kọrinti Kinni 7

Kọrinti Kinni 7:28-35