Kọrinti Kinni 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bóyá n óo dúró lọ́dọ̀ yín, mo tilẹ̀ lè wà lọ́dọ̀ yín ní àkókò òtútù, kí ẹ lè sìn mí lọ sí ibi tí mo bá tún ń lọ.

Kọrinti Kinni 16

Kọrinti Kinni 16:5-7