Kọrinti Kinni 15:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó bá hù kì í rí bí ohun tí a gbìn ti rí, nítorí pé irúgbìn lásán ni, ìbáà ṣe àgbàdo tabi àwọn ohun ọ̀gbìn yòókù.

Kọrinti Kinni 15

Kọrinti Kinni 15:27-44