Kọrinti Kinni 11:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi, nígbà tí ẹ bá péjọ láti jẹun, ẹ máa dúró de ara yín.

Kọrinti Kinni 11

Kọrinti Kinni 11:24-34