Kọrinti Keji 5:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ Ọlọrun ni èyí láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin. Òun ni ó ti là wá níjà pẹlu ara rẹ̀ nípasẹ̀ Kristi. Òun kan náà ni ó tún fún wa ní iṣẹ́ ìlàjà ṣe.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:10-21