Kọrinti Keji 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kò ṣòro fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ láti farahàn bí iranṣẹ tòótọ́. Ṣugbọn ìgbẹ̀yìn wọn yóo rí bí iṣẹ́ wọn.

Kọrinti Keji 11

Kọrinti Keji 11:5-16