Kolose 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé mo jẹ́rìí rẹ̀ pé ó ti ṣiṣẹ́ pupọ fun yín ati fún àwọn tí ó wà ní Laodikia ati ní Hierapoli.

Kolose 4

Kolose 4:10-16