Kolose 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní àkókò yìí, ẹ pa gbogbo àwọn nǹkan wọnyi tì: ibinu, inúfùfù, ìwà burúkú, ìsọkúsọ, ọ̀rọ̀ ìtìjú.

Kolose 3

Kolose 3:4-12