Joṣua 8:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà Joṣua ka gbogbo òfin náà sókè ati ibukun tí ó wà ninu rẹ̀, ati ègún, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti kọ ọ́ sinu ìwé òfin.

Joṣua 8

Joṣua 8:30-35