Joṣua 7:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua wí fún Akani pé, “Ọmọ mi, fi ògo fún OLUWA Ọlọrun Israẹli, kí o sì yìn ín. Jẹ́wọ́ ohun tí o ṣe, má fi pamọ́ fún mi.”

Joṣua 7

Joṣua 7:18-26