Joṣua 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kinni ni àwọn eniyan náà gun òkè odò Jọdani. Wọ́n pàgọ́ sí Giligali ní ìhà ìlà oòrùn Jẹriko.

Joṣua 4

Joṣua 4:13-24