Joṣua 18:22-27 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Betaraba, Semaraimu, Bẹtẹli;

23. Afimu, Para, Ofira;

24. Kefariamoni, Ofini, ati Geba; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mejila.

25. Gibeoni, Rama, Beeroti

26. Misipa, Kefira, Mosa;

27. Rekemu, Iripeeli, Tarala;

Joṣua 18