Joṣua 15:31-34 BIBELI MIMỌ (BM)

31. Sikilagi, Madimana, Sansana;

32. Lebaotu, Ṣilihimu, Aini ati Rimoni; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkandinlọgbọn.

33. Àwọn ìlú wọn tí wọ́n wà ní ẹsẹ̀ òkè nìwọ̀nyí: Eṣitaolu, Sora, Aṣinai.

34. Sanoa, Enganimu, Tapua, Enamu;

Joṣua 15