Joṣua 12:23-24 BIBELI MIMỌ (BM) Dori, tí ó wà ní etí òkun; Goiimu, tí ó wà ní Galili, ati Tirisa. Gbogbo wọn jẹ́ ọba mọkanlelọgbọn.