Johanu 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwa kò mọ̀ bí ó ti ṣe wá ń ríran nisinsinyii. Ẹ bi í, kì í ṣe ọmọde, yóo fi ẹnu ara rẹ̀ sọ bí ó ti rí.”

Johanu 9

Johanu 9:16-27