Johanu 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn eléyìí kò lè jẹ́ Mesaya, nítorí a mọ ibi tí ó ti wá. Nígbà tí Mesaya bá dé, ẹnikẹ́ni kò ní mọ ibi tí ó ti wá.”

Johanu 7

Johanu 7:17-33