Johanu 4:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu wí fún un pé, “Máa lọ, ọmọ rẹ yóo yè.”Ọkunrin náà gba ọ̀rọ̀ tí Jesu sọ fún un gbọ́, ó bá ń lọ sílé.

Johanu 4

Johanu 4:45-54