Johanu 4:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ran yín láti kórè níbi tí ẹ kò ti ṣiṣẹ́ ọ̀gbìn. Àwọn ẹnìkan ti ṣiṣẹ́, ẹ̀yin wá ń jèrè iṣẹ́ wọn.”

Johanu 4

Johanu 4:37-45