Johanu 20:8-10 BIBELI MIMỌ (BM)

8. Ọmọ-ẹ̀yìn keji tí ó kọ́kọ́ dé ẹnu ibojì náà bá wọ inú ibojì; òun náà rí i, ó wá gbàgbọ́.

9. (Nítorí ohun tí Ìwé Mímọ́ wí kò tíì yé wọn pé dandan ni kí ó jí dìde ninu òkú.)

10. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn bá tún pada lọ sí ilé wọn.

Johanu 20