Johanu 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bẹ̀rẹ̀ ó yọjú wo inú ibojì, ó rí aṣọ-ọ̀gbọ̀ tí ó wà nílẹ̀, ṣugbọn kò wọ inú ibojì.

Johanu 20

Johanu 20:2-6