Johanu 19:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọgbà kan wà níbi tí wọ́n ti kan Jesu mọ́ agbelebu. Ibojì titun kán wà ninu ọgbà náà, wọn kò ì tíì sin òkú kankan sinu rẹ̀ rí.

Johanu 19

Johanu 19:35-42