Johanu 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii mò ń lọ sọ́dọ̀ ẹni tí ó rán mi níṣẹ́. Ẹnìkankan ninu yín kò wí pé, ‘Níbo ni ò ń lọ?’

Johanu 16

Johanu 16:3-12