Johanu 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Àjọ̀dún Ìrékọjá ku ọjọ́ mẹfa, Jesu lọ sí Bẹtani níbi tí Lasaru wà, ẹni tí ó kú, tí Jesu jí dìde.

Johanu 12

Johanu 12:1-10