Johanu Kinni 5:20-21 BIBELI MIMỌ (BM)

20. A tún mọ̀ pé Ọmọ Ọlọrun ti dé, ó ti fún wa ní làákàyè kí á lè mọ ẹni Òtítọ́. À ń gbé inú Ọlọrun, àní inú Ọmọ rẹ̀, Jesu Kristi. Òun ni Ọlọrun tòótọ́ ati ìyè ainipẹkun.

21. Ẹ̀yin ọmọde, ẹ má bá wọn bọ oriṣa.

Johanu Kinni 5