Jobu 9:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun kì í ṣe eniyan bíì mi,tí mo fi lè fún un lésì,tí a fi lè jọ rojọ́ ní ilé ẹjọ́.

Jobu 9

Jobu 9:24-35