Jobu 6:27-29 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Ẹ tilẹ̀ lè ṣẹ́ gègé lórí ọmọ òrukàn,ẹ sì lè díye lé ọ̀rẹ́ yín.

28. “Ẹ gbọ́, ẹ wò mí dáradára,nítorí n kò ní purọ́ níwájú yín.

29. Mo bẹ̀ yín, ẹ dúró bẹ́ẹ̀,kí ẹ má baà ṣẹ̀.Ẹ dúró bẹ́ẹ̀, nítorí n kò lẹ́bi.

Jobu 6