Jobu 6:24-26 BIBELI MIMỌ (BM)

24. “Ó dára, mo gbọ́, ẹ wá kọ́ mi,ẹ ṣàlàyé ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀ fún mi;n óo sì dákẹ́ n óo tẹ́tí sílẹ̀.

25. Lóòótọ́ ọ̀rọ̀ òtítọ́ ní agbára,ṣugbọn kí ni ẹ̀ ń bá mi wí lé lórí.

26. Ẹ rò pé mò ń fi ọ̀rọ̀ ṣòfò lásán ni?Kí ni ẹ̀ ń dásí ọ̀rọ̀ èmi onírora sí?

Jobu 6