Jobu 5:26-27 BIBELI MIMỌ (BM)

26. O óo di arúgbó kí o tó kú,gẹ́gẹ́ bí ọkà tií gbókí á tó kó o wá síbi ìpakà.

27. Wò ó! A ti wádìí àwọn nǹkan wọnyi,òtítọ́ ni wọ́n.Gbọ́, kí o sì mọ̀ pé fún ire ara rẹ ni.”

Jobu 5