Jobu 41:33-34 BIBELI MIMỌ (BM) Kò sí ohun tí a lè fi wé láyé,ẹ̀dá tí ẹ̀rù kì í bà. Ó fojú tẹmbẹlu gbogbo ohun gíga,ó sì jọba