Jobu 40:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA tún sọ fún Jobu pé,

2. “Ṣé ẹni tí ń bá eniyan rojọ́ lè bá Olodumare rojọ́?Kí ẹni tí ń bá Ọlọrun jiyàn dáhùn.”

3. Nígbà náà ni Jobu dá OLUWA lóhùn, ó ní:

Jobu 40