Jobu 4:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Nígbà náà ni Elifasi, ará Temani, dá Jobu lóhùn, ó ní:

2. “Bí eniyan bá bá ọ sọ̀rọ̀,ṣé kò ní bí ọ ninu?Àbí eniyan ha lè dákẹ́ bí?

3. O ti kọ́ ọpọlọpọ eniyan,o ti fún aláìlera lókun.

Jobu 4