Jobu 37:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, a gbọ́ ìró ohùn rẹ̀,ó sọ̀rọ̀ ninu ọlá ńlá rẹ̀,bí ìgbà tí ààrá bá sán,sibẹsibẹ kò dá mànàmáná dúróbí àwọn eniyan ti ń gbóhùn rẹ̀.

Jobu 37

Jobu 37:3-7