Jobu 37:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwámárìídìí ni Olodumare–agbára ati ìdájọ́ òtítọ́ rẹ̀ pọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kì í kọ òdodo sílẹ̀.

Jobu 37

Jobu 37:22-24