Jobu 36:16 BIBELI MIMỌ (BM)

A máa yọ ọ́ kúrò ninu ìpọ́njú,bọ́ sinu ìdẹ̀ra níbi tí kò sí wahala,oúnjẹ tí a gbé kalẹ̀ níwájú rẹ̀ a sì jẹ́ kìkì àdídùn.

Jobu 36

Jobu 36:11-19