Jobu 32:20-22 BIBELI MIMỌ (BM) Mo níláti sọ̀rọ̀ kí ara lè rọ̀ mí,mo gbọdọ̀ la ẹnu mi kí n sì dáhùn. N kò ní ṣe ojuṣaaju