Jobu 32:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, ní ìdílé Ramu bá bínú sí Jobu, nítorí pé ó dá ara rẹ̀ láre dípò Ọlọrun.

Jobu 32

Jobu 32:1-12