Jobu 30:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń dún bíi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ninu igbó,wọ́n ń kó ara wọn jọ sí abẹ́ igi ẹlẹ́gùn-ún.

Jobu 30

Jobu 30:1-10