Jobu 25:5-6 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Wò ó, òṣùpá pàápàá kò mọ́lẹ̀ tó,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìràwọ̀ kò mọ́ tó lójú rẹ̀;

6. kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ ti eniyan tí ó dàbí ìdin,tabi ọmọ eniyan tí ó dàbí ekòló lásánlàsàn!”

Jobu 25