Jobu 22:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Elifasi ará Temani bá dáhùn pé,

2. “Ǹjẹ́ eniyan lè wúlò fún Ọlọrun?Nítòótọ́, bí eniyan tilẹ̀ jẹ́ ọlọ́gbọ́n, ara rẹ̀ ni ó wúlò fún.

Jobu 22