Jobu 17:15-16 BIBELI MIMỌ (BM)

15. níbo ni ìrètí mi wá wà?Ta ló lè rí ìrètí mi?

16. Ṣé yóo lọ sí ọ̀gbun àìnísàlẹ̀ ni?Ṣé àwa mejeeji ni yóo jọ wọ inú erùpẹ̀ lọ?”

Jobu 17