Jobu 16:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá wà ní ipò mi,èmi náà lè sọ̀rọ̀ bí ẹ tí ń sọ̀rọ̀ yìí,kí n da ọ̀rọ̀ bò yín,kí n sì máa mi orí si yín.

Jobu 16

Jobu 16:1-11