Jobu 16:20-22 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Àwọn ọ̀rẹ́ mi ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà,mo sì ń sọkún sí Ọlọrun,

21. ìbá ṣe pé ẹnìkan lè ṣe alágbàwí fún ẹnìkejì lọ́dọ̀ Ọlọrun,bí eniyan ti lè ṣe alágbàwí fún ẹnìkejì rẹ̀ níwájú eniyan.

22. Lẹ́yìn ọdún díẹ̀ sí i,n óo lọ àjò àrèmabọ̀.

Jobu 16